Lɛ́kpasɛ̀ ìwé Ìmùlɛ̀ Tètè an ɔ́, àá ti tú ìwé Ìkpìlɛ̀ ayé, ìwé Rùútù, ìwé Jonásì, ìwé Neemíì, ìwé Ɛsidrásì, ìwé Ìrìn àjò, ìwé àkpàshɛ̀ kánná ìwé èkéjì samuɛ́lì. Iín ɛ yɔ́ɔ gbà án si líìtá ɛ̀rɔ ín líbibí.
Ìwé Ìkpìlɛ̀ ayé (1.18 Mo)